Home iwaasu awoṣe 1 Kọ́ríńtì 2:9 BMY – Ohun tí ojú kò tí ì rí, tí etí kò sì tí ì gbọ́, tí kò sì wọ inú ọkàn ènìyàn, ohun tí Ọlọ́run ti pèsè sílẹ̀ fún àwọn tí ó fẹ́ràn rẹ̀.